SOSTIENICI CON UN'OFFERTA TRAMITE PAYPAL
IGI KERESIMESI TO TOBI JU NI GBOGBO ABGA AIYE .
GUBBIO wa’ ni ara awon ilu el?wa aiye atijo ti oni ododo, ni inu ilu alaw? ewe Umbria, ni arin
okan Itali, Ilu Gubbio ni iranse Oluwa Francesiko ti pade ati ntù ereko Ikooko kan.
Ni ati odun aad?run ?g?rin ?kan, ni awon egb? ara ilu no’ ti bere tinse igi keresimesi ti o tobi ju ni gbogbo ile aiye ,……….
Igi na wa ni enu oke ilu na, ni oke Ingino , lati ibe wa le, gbogbo eniyan ma wo aworan igi na pelu pelu awon ?p?l?p? globu ti orisirisi oda .
?dunrun , ni iye ina ti oda alaw? ewe ti oyii igi na ka.
meje ?g?run ati aad?ta, ni giga igi na
irinwo, ni ina oda imole orisirisi ti owa ni inu ati arin igi naa ,
ni ori oke igi na, aori irawo unla repete pelu imole ti oju meji ?g?run ati aad?ta lo,
Ni ati odun aad?run ?ni ?kandil?g?runitan, iroyin nipa igi na wa ni kiko ninu iwe iyi ati oye gbogbo ile aiye, igi na maa wa ni tita lati ojo keje ti osu ikejila dii ojo ikefa osu ikini, ni gbogbo odu,
Ni gbogbo odun awon eniyan lati orisirisi ilu ni ile aiye ma waa wo ina keresimesi na ni igba odun.
Aw?n n?mba
Aad?run ?g?rin ?kan , odun ti won daa sile
Okan ?gb?run Ni aaye ti irawo na gba
Meji ?g?run ati aad?ta Ni iye ina ni won fi yikaa
Odunrun Ni iye ina ap?r? e,
Irinwo Ni iye ina imole ti oda orisirisi ti o wa ni inu awora igi na
Meje ?gb?run marun ?g?run Ni gungun okun ina ti won lo ,
Meje ?g?run ati aad?ta Ni giga igi na,
Irinwo ati ki o aad?ta Ni titobi iga na lati isale soke,
Okan ?gb?run meta ?g?run ati aad?ta Ni op?l?p? owun lilo lati jeki imole ina igi na too,
Aad?ta Ni awon eniyan ti won sise fun ayori igi keresimesi na.
Meje Awon meje lo dari ise na
Meji ?gb?run ?kan ?g?run Ni eye wakati aseyori ,
Ogb?n marun Ni agbara ina oyinbo ti won loo,
Aad?run m?j? Loni Ni iye awon oni irowin lati gbogbo agba wa, ti won royin
nipa igi keresimesi na.
ODUN AYA ABO. ASEYISAMODUN.